Ọlọ́run ti kọ́ wa ní ọ̀nà ìgbàlà nígbà gbogbo pẹ̀lú àwọn àsọtẹ́lẹ̀ nípa àjálù.
Nípasẹ̀ ìtàn ìgbà ayé Mósè, nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́ ẹrú, àti ìtàn Ísírẹ́lì àríwá àti Júdà gúúsù, Ó jẹ́ kí a mọ̀ pé ọ̀nà kan ṣoṣo tí a lè gbà bọ́ nínú àjálù ni Ìrékọjá.
Lónìí, Ìjọ Ìpínlẹ̀ Míṣọ̀nàrì Àgbáyé ti Ọlọ́run ni ilé-ijọsin kan ṣoṣo tí ó ń ṣe Ìrékọjá nípa àkàrà àti ọtí-wáìnì ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní nípa kalẹ́ńdà mímọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀kọ́ Jesu.
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ lẹ́yìn oúnjẹ alẹ́, ó sì mú ago wáìnì, ó wí pé, “Ago yìí ni májẹ̀mú tuntun nínú ẹ̀jẹ̀ mi, tí a ta sílẹ̀ fún yín.”
Luku 22:20
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy