Ọlọ́run sọ pé òun yóò lo orúkọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta náà títí di òpin ayé—orúkọ Baba, Ọmọ, àti ti Ẹ̀mí Mímọ́; nígbà àkókò Baba, Jèhófà ni, àti nígbà àkókò Ọmọ, Jesu ni.
Jesu jẹ́ kí a mọ̀ pé orúkọ tuntun Rẹ̀ yóò farahàn ní ọjọ́ iwájú, àti pé àwọn ẹni mímọ́ nìkan ni a ó fi fún.
Orúkọ tuntun Jesu ni orúkọ Ọlọrun ní àkókò Ẹ̀mí Mímọ́.
Nínú Ìjọ Ọlọ́run nìkan la lè mọ orúkọ tuntun Jesu, ìyẹn orúkọ Ẹ̀mí Mímọ́, kí a sì ṣe ìrìbọmi ní orúkọ Baba, Ọmọ, àti ti Ẹ̀mí Mímọ́ láti rin ipa ọ̀nà ìgbàlà.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy