Ní àkókò ìṣẹ̀dá ọlọ́jọ́ mẹ́fà, Ọlọ́run dá ẹran ọ̀sìn àti ẹranko igbó, ó sì dá Adamu àti Efa ní ìkẹ́yìn gbogbo wọn ní ọjọ́ kẹfà.
Èyí jẹ́ láti jẹ́rìí nípa Adamu àti Efa alásọtẹ́lẹ̀—Ẹ̀mí àti Ìyàwó tí yóò farahàn ní sànmánì Ẹ̀mí Mímọ́ láti fún aráyé ní omi ìyè.
Ile ijọsin Ọlọrun gbagbọ ninu Adamu tí ó kẹ́yìn, Wiwa Keji Kristi Ahnsahnghong, àti Efa tí ó kẹ́yìn, Ọlọrun Iya.
Ṣùgbọ́n ikú jẹ ọba láti ìgbà Adamu wá títí fi di ìgbà ti Mose, àti lórí àwọn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn kò dàbí irú ìrékọjá Adamu, ẹni tí í ṣe àpẹẹrẹ ẹni tí ń bọ̀.
Romu 5:14
Adamu sì sọ aya rẹ̀ ní Efa nítorí òun ni yóò di ìyá gbogbo alààyè.
Gẹnẹsisi 3:20
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy