Àwọn ẹni-àyélẹ́tà ńlá kan wà tí gbogbo èèyàn ilẹ̀-àyé ń ṣàṣeyọrí fún lọ́wọ́lọ́wọ́ yìí gẹ́gẹ́ bí Galileo Galilei onímọ̀-jinlẹ̀ ńlá tí ó ṣe tẹliskọopu, Joan ti Arc akínkanjú orílẹ̀-èdè tí ó gba France là ní Ogun Ọdún Ọgọrun, Àpóstélì Pọ́ọ̀lù àpẹrẹ igbagbọ́ fún gbogbo àwọn Kristiani ilẹ̀-àyé, àti Jesu Kristi tí ó wá nínú ẹran ara láti gba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ là ní ọdún 2,000 sẹ́yìn.
Bí ó ti wù kí ó rí, gbogbo wọn ni wọ́n pè ní aládàámọ̀ nípasẹ̀ agbára ìsìn àkókò yẹn.
Nígbà náà, kí ni nípa ti World Mission Society Church of God?
Ṣe ó jẹ́ aládàámọ̀ ní tàbí òótọ́?
Ó jẹ́ ìjọ òótọ́ tí Ọlọ́run dá sílẹ̀, ó sì ní òtítọ́ májẹ̀mú tuntun.
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy