Kò sí ohun kan lórí ilé ayé tó lè wà láìní omi.
Lóòótọ́ gbọ́dọ̀ rí, bí a kò bá pèsè omi ìyè fún ọkàn wa—ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, a óò jìyà òùngbẹ tẹ̀mí a ó sì ṣègbé nígbẹ̀yìngbẹ́yín.
Nínú Bíbélì, ó kọ nípé Ẹ̀mí àti Ìyàwó ń fún ní omi ìyè.
Níhìn-ín, Ìyàwó jẹ́ Ọlọ́run—orísun omi ìyè, kì í ṣe ṣọ́ọ̀ṣì tàbí àwọn onígbàgbọ́.
Nìkan nínú Ìjọ Ọlọ́run, tí ó gbàgbọ́ nínú Ẹ̀mí àti Ìyàwó—Wíwà Kejì Jésù Kristi Ahnsahnghong àti Ọlọrun Ìyá—tí ó wá nínú ẹ̀dá láyé ní àkókò yìí, ni a lè rí omi ìyè.
Ẹ̀mí àti ìyàwó wí pé, “Máa bọ!” Àti ẹni tí ó ń gbọ́ kí ó wí pé, “Máa bọ̀!” Àti ẹni tí òǹgbẹ ń gbẹ kí ó wá, àti ẹni tí o bá sì fẹ́, kí ó gba omi ìyè náà lọ́fẹ̀ẹ́.
Ìfihàn 22:17
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy