Gbogbo aye n se ayeye ibi Jesu ni gbogbo Oṣù-òpẹ 25, Keresimesi.
Síbẹ̀, kò sí ẹsẹ kan tí ó sọ pé a bí Jesu ní Oṣù-òpẹ 25 ní Bibeli.
Nípasẹ̀ ìtàn, a lè lóye pé Keresimesi bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́-ibi òrìṣà-ẹsẹ̀ Mithra.
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọlọ́run tí Kristi Ahnsahnghong, ẹni tí ó wá ni èkejì gbé kalẹ̀, kì í ṣe ayẹyẹ Keresimesi, ọjọ́-ibi òrìṣà-oorun, èyí tí kò wà ní Bibeli.
“Oṣù-òpẹ 25 kii ṣe ọjọ́-ibi Jesu, ṣugbọn ti Òrìṣà-oorun.
Keresimesi jẹ́ ìtàn àjọ ìṣìn àìsìn fún oorun tí a kìí le bori.”
-Encyclopedia Britannica-
“Keresimesi kò jẹ́ kí Ọlọ́run dá a sí, bẹ́ẹ̀ ni kò dá lé Bibeli lórí.”
-Cyclopedia ti Bibeli, Theological ati ti Oniwa litireso-
119 Bundang P.O.Box, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of KOREA
Tel 031-738-5999 Fax 031-738-5998
Head Office: 50, Sunae-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
Main Church: 35, Pangyoyeok-ro, Bundang-gu, Seongnam-si, Gyeonggi-do, Rep. of Korea
ⓒ World Mission Society Church of God. All rights reserved. Privacy Policy